Isikiẹli 43:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí wọ́n pa ìwà ìbọ̀rìṣà wọn tì, kí wọ́n sì gbé òkú àwọn ọba wọn jìnnà sí mi, n óo sì máa gbé ààrin wọn títí lae.

Isikiẹli 43

Isikiẹli 43:1-17