Isikiẹli 43:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, ṣe àpèjúwe Tẹmpili yìí, sọ bí ó ti rí ati àwòrán kíkọ́ rẹ̀ fún àwọn ọmọ Israẹli, kí ojú ẹ̀ṣẹ̀ wọn lè tì wọ́n.

Isikiẹli 43

Isikiẹli 43:9-13