Isikiẹli 43:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìran tí mo rí yìí dàbí èyí tí mo rí nígbà tí Ọlọrun wá pa ìlú Jerusalẹmu run ati bí ìran tí mo rí létí odò Kebari; mo bá dojúbolẹ̀.

Isikiẹli 43

Isikiẹli 43:1-4