Isikiẹli 43:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! Ìtànṣán ògo Ọlọrun Israẹli yọ láti apá ìlà oòrùn, ìró bíbọ̀ rẹ̀ dàbí ti omi òkun, ìmọ́lẹ̀ ògo rẹ̀ sì tàn sórí ilẹ̀.

Isikiẹli 43

Isikiẹli 43:1-9