Isikiẹli 43:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Orí pẹpẹ náà ní igun mẹrin, òòró rẹ̀ jẹ́ igbọnwọ mejila (mita mẹfa) ìbú rẹ̀ sì jẹ́ igbọnwọ mejila (mita mẹfa).

Isikiẹli 43

Isikiẹli 43:12-19