Isikiẹli 43:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Orí pẹpẹ náà ga ní igbọnwọ mẹrin (mita meji). Ìwo mẹrin wà lára rẹ̀, wọ́n gùn ní igbọnwọ kọ̀ọ̀kan (ìdajì mita kan).

Isikiẹli 43

Isikiẹli 43:12-18