Isikiẹli 42:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn yàrá ti gbọ̀ngàn ìta gùn ní aadọta igbọnwọ (mita 25), ṣugbọn àwọn tí wọ́n wà níwájú tẹmpili jẹ́ ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 50).

Isikiẹli 42

Isikiẹli 42:1-10