Isikiẹli 42:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ògiri kan wà ní ìta tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ àwọn yàrá ní apá ti gbọ̀ngàn ìta, ó wà níwájú àwọn yàrá náà, gígùn rẹ̀ jẹ́ aadọta igbọnwọ, (mita 25).

Isikiẹli 42

Isikiẹli 42:2-17