Isikiẹli 42:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nísàlẹ̀ àwọn yàrá ìhà gúsù, ọ̀nà kan wà ní apá ìlà oòrùn. Bí eniyan bá wọ àlàfo náà, ògiri kan dábùú rẹ̀ níwájú.

Isikiẹli 42

Isikiẹli 42:8-20