Isikiẹli 42:11 BIBELI MIMỌ (BM)

ọ̀nà wà níwájú wọn. Wọ́n rí bí àwọn yàrá ti ìhà àríwá, òòró ati ìbú wọn rí bákan náà. Bákan náà ni ẹnu ọ̀nà wọn rí, ati ìlẹ̀kùn wọn.

Isikiẹli 42

Isikiẹli 42:1-18