Isikiẹli 40:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú mi lọ sí ilẹ̀ Israẹli ninu ìran, ó gbé mi sí orí òkè gíga kan. Ó dàbí ẹni pé ìlú kan wà ní ìhà ìsàlẹ̀ òkè náà.

Isikiẹli 40

Isikiẹli 40:1-6