Isikiẹli 40:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹwaa oṣù kinni, ọdún kẹẹdọgbọn tí a ti wà ní ìgbèkùn, tíí ṣe ọdún kẹrinla tí ogun fọ́ ìlú Jerusalẹmu, agbára OLUWA sọ̀kalẹ̀ sára mi.

Isikiẹli 40

Isikiẹli 40:1-8