Isikiẹli 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! N óo dè ọ́ lókùn mọ́lẹ̀, tí o kò fi ní lè yí ẹ̀gbẹ́ pada títí tí o óo fi parí iye ọjọ́ tí o níláti fi gbé ogun tì í.

Isikiẹli 4

Isikiẹli 4:1-10