Isikiẹli 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lẹ́yìn náà, kọjú sí Jerusalẹmu, ìlú tí a gbógun tì, ká aṣọ kúrò ní apá rẹ kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí i.

Isikiẹli 4

Isikiẹli 4:1-14