Isikiẹli 39:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, n óo gbọn ọrun rẹ dànù lọ́wọ́ òsì rẹ; n óo sì gbọn ọfà bọ́ sílẹ̀ lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ.

Isikiẹli 39

Isikiẹli 39:1-4