Isikiẹli 39:2 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo yí ọ pada, n óo lé ọ siwaju, n óo mú ọ wá láti òpin ìhà àríwá, o óo wá dojú kọ àwọn òkè Israẹli.

Isikiẹli 39

Isikiẹli 39:1-6