Isikiẹli 36:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹ̀yin òkè Israẹli, igi óo hù lórí yín, wọn óo sì so èso fún Israẹli, àwọn eniyan mi, nítorí pé wọn kò ní pẹ́ pada wálé.

Isikiẹli 36

Isikiẹli 36:1-16