Isikiẹli 36:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, èmi OLUWA Ọlọrun, ń ṣe ìbúra pé, àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà ní àyíká yín yóo di ẹni ẹ̀sín.

Isikiẹli 36

Isikiẹli 36:6-11