Isikiẹli 35:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wí fún un pé OLUWA Ọlọrun ní,‘Wò ó! Mo lòdì sí ọ,ìwọ Òkè Seiri.N óo nawọ́ ibinu sí ọ,n óo sọ ọ́ di ahoro ati aṣálẹ̀.

Isikiẹli 35

Isikiẹli 35:1-5