Isikiẹli 34:26 BIBELI MIMỌ (BM)

“N óo bukun àwọn, ati gbogbo agbègbè òkè mi. N óo máa jẹ́ kí òjò máa rọ̀ lásìkò wọn, òjò ibukun ni yóo sì máa jẹ́.

Isikiẹli 34

Isikiẹli 34:21-28