Isikiẹli 34:25 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo bá wọn dá majẹmu alaafia; n óo lé àwọn ẹranko burúkú kúrò ní ilẹ̀ náà, wọn yóo máa gbé inú aṣálẹ̀ ati inú igbó láìléwu.

Isikiẹli 34

Isikiẹli 34:18-31