Isikiẹli 33:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí eniyan burúkú bá sì yipada kúrò ninu ibi tí ó ń ṣe, tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ohun tí ó dára tí ó sì tọ́, yóo yè nítorí rere tí ó ṣe.

Isikiẹli 33

Isikiẹli 33:17-23