Isikiẹli 33:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí olódodo bá yipada kúrò ninu ìwà òdodo rẹ̀, tí ó bá ń dẹ́ṣẹ̀, yóo kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.

Isikiẹli 33

Isikiẹli 33:10-19