Isikiẹli 30:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“ ‘Àwọn ará Etiopia, ati Puti, ati Ludi, ati gbogbo ilẹ̀ Arabia ati Libia, ati gbogbo àwọn eniyan wa tí wọ́n jọ gbìmọ̀ pọ̀, ni ogun yóo pa.’ ”

Isikiẹli 30

Isikiẹli 30:1-7