Isikiẹli 30:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun yóo jà ní Ijipti,ìrora yóo sì bá Etiopia.Nígbà tí ọpọlọpọ òkú bá sùn ní Ijipti,tí a kó ọrọ̀ rẹ̀ lọ,tí a sì wó ìpìlẹ̀ rẹ̀ lulẹ̀.

Isikiẹli 30

Isikiẹli 30:1-14