Isikiẹli 3:26 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo mú kí ahọ́n rẹ lẹ̀ mọ́ ọ lẹ́nu kí o sì ya odi, kí o má baà lè kìlọ̀ fún wọn, nítorí pé ìdílé ọlọ̀tẹ̀ ni ìdílé wọn.

Isikiẹli 3

Isikiẹli 3:18-27