Isikiẹli 3:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ọmọ eniyan, wò ó! A óo na okùn lé ọ lórí, a óo sì fi okùn náà dè ọ́, kí o má baà lè jáde sí ààrin àwọn eniyan.

Isikiẹli 3

Isikiẹli 3:18-27