Isikiẹli 3:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá dìde, mo jáde lọ sí àfonífojì. Mo rí ìfarahàn ògo OLUWA níbẹ̀, gẹ́gẹ́ bí mo ti rí i lẹ́bàá odò Kebari, mo bá dojúbolẹ̀.

Isikiẹli 3

Isikiẹli 3:22-27