Isikiẹli 3:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀mí OLUWA sì wà lára mi, ó sọ fún mi pé, “Dìde, lọ sí àfonífojì, níbẹ̀ ni n óo ti bá ọ sọ̀rọ̀.”

Isikiẹli 3

Isikiẹli 3:21-23