Isikiẹli 3:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Lọ bá àwọn eniyan rẹ tí wọ́n wà ní ìgbèkùn, kí o sọ ohun tí OLUWA Ọlọrun sọ fún wọn; wọn ìbáà gbọ́, wọn ìbáà má sì gbọ́.”

Isikiẹli 3

Isikiẹli 3:5-13