Isikiẹli 3:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún sọ fún mi, pé, “Ọmọ eniyan, fi etí sí gbogbo ọ̀rọ̀ tí n óo bá ọ sọ, kí o sì fi wọ́n sọ́kàn.

Isikiẹli 3

Isikiẹli 3:5-14