Isikiẹli 3:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ó sọ fún mi pé, “Ọmọ Eniyan, jẹ ohun tí a fún ọ; jẹ ìwé tí a ká yìí, kí o sì lọ bá ilé Israẹli sọ̀rọ̀.”

2. Mo bá la ẹnu, ó sì fún mi ní ìwé náà jẹ.

Isikiẹli 3