Isikiẹli 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún mi pé, “Ọmọ Eniyan, jẹ ohun tí a fún ọ; jẹ ìwé tí a ká yìí, kí o sì lọ bá ilé Israẹli sọ̀rọ̀.”

Isikiẹli 3

Isikiẹli 3:1-6