Isikiẹli 27:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Igi firi láti Seniri ni wọ́n fi ṣe gbogbo ẹ̀gbẹ́ rẹ.Igi kedari láti Lẹbanoni ni wọ́n sì fi ṣe òpó ọkọ̀ rẹ.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:1-8