Isikiẹli 27:35 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹnu ya gbogbo àwọn tí ń gbé etí òkun nítorí ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí ọ. Àwọn ọba wọn ń gbọ̀n jìnnìjìnnì, ẹ̀rù sì hàn ní ojú wọn.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:29-36