Isikiẹli 27:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Wàyí ò, omi òkun ti fọ́ ọ sí wẹ́wẹ́,o ti rì sí ìsàlẹ̀ òkun.’Gbogbo àwọn ọjà rẹati àwọn tí ń wa ọkọ̀ rẹ ti rì pẹlu rẹ.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:25-35