Isikiẹli 25:9 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí náà, n óo tú àwọn ìlú Moabu tí wọ́n wà ní apá ọ̀tún ati apá òsì ká: àwọn ìlú tí ó dára jù ní ilẹ̀ Moabu, Beti Jẹṣimoti, Baali Meoni ati Kiriataimu ká.

Isikiẹli 25

Isikiẹli 25:5-13