Isikiẹli 25:8 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní, “Àwọn ará Moabu ń wí pé ilẹ̀ Juda dàbí àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn,

Isikiẹli 25

Isikiẹli 25:2-13