Isikiẹli 23:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé OLUWA Ọlọrun ní, “Ẹ pe ogunlọ́gọ̀ eniyan lé wọn lórí kí wọ́n ṣẹ̀rù bà wọ́n, kí wọ́n sì kó wọn lẹ́rù;

Isikiẹli 23

Isikiẹli 23:40-49