Isikiẹli 23:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn olódodo eniyan ni yóo dá àwọn obinrin náà lẹ́jọ́ panṣaga, ati ti apànìyàn, nítorí pé panṣaga eniyan ni wọ́n, wọ́n sì ti paniyan.”

Isikiẹli 23

Isikiẹli 23:38-49