Isikiẹli 22:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan inú rẹ ń parọ́ láti paniyan. Wọ́n ń jẹbọ kiri lórí àwọn òkè ńláńlá, wọ́n sì ń ṣe ohun ìtìjú.

Isikiẹli 22

Isikiẹli 22:5-13