Isikiẹli 22:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mìíràn ń bá aya baba wọn lòpọ̀, wọ́n sì ń fi ipá bá obinrin lòpọ̀ ní ìgbà tí ó ń ṣe nǹkan oṣù rẹ̀ lọ́wọ́.

Isikiẹli 22

Isikiẹli 22:1-20