Isikiẹli 22:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá ẹnìkan láàrin wọn tí ìbá tún odi náà mọ, kí ó sì dúró níbi tí odi ti ya níwájú mi láti bẹ̀bẹ̀ fún ilẹ̀ náà, kí n má baà pa á run, ṣugbọn n kò rí ẹnìkan.

Isikiẹli 22

Isikiẹli 22:24-31