Isikiẹli 22:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan ilẹ̀ náà ń fi ipá gba nǹkan-oní-nǹkan; wọ́n ń ni talaka ati aláìní lára, wọ́n sì ń fi ipá gba nǹkan lọ́wọ́ àwọn àlejò láì ṣe àtúnṣe.

Isikiẹli 22

Isikiẹli 22:20-31