Isikiẹli 21:32 BIBELI MIMỌ (BM)

O óo di nǹkan ìdáná, lórí ilẹ̀ yín ni a óo pa yín sí, ẹ óo sì di ẹni ìgbàgbé, èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.’ ”

Isikiẹli 21

Isikiẹli 21:25-32