Isikiẹli 21:31 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo bínú sí ọ lọpọlọpọ, ìrúnú mi yóo jó ọ bí iná, n óo fà ọ́ lé àwọn oníjàgídíjàgan lọ́wọ́, àwọn tí wọ́n mọ̀ bí wọ́n ṣe ń panirun.

Isikiẹli 21

Isikiẹli 21:25-32