Isikiẹli 20:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, mo ṣe ìlérí fún wọn ninu aṣálẹ̀ pé n óo fọ́n wọn káàkiri láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù,

Isikiẹli 20

Isikiẹli 20:17-25