Isikiẹli 20:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn mo rowọ́, mo sì ro ti orúkọ mi, tí n kò fẹ́ kí wọ́n bàjẹ́ lójú àwọn orílẹ̀-èdè tí mo ti kó wọn jáde.

Isikiẹli 20

Isikiẹli 20:15-31