Isikiẹli 20:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ní èmi OLUWA ni Ọlọrun yín. Ẹ máa rìn ní ọ̀nà mi, kí ẹ sì máa pa òfin mi mọ́.

Isikiẹli 20

Isikiẹli 20:17-27