Isikiẹli 20:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo sọ fún àwọn ọmọ wọn ninu aṣálẹ̀ pé kí wọ́n má tọ ọ̀nà tí àwọn baba wọn rìn, kí wọ́n má ṣe tẹ̀lé òfin wọn, tabi kí wọ́n bọ oriṣa wọn.

Isikiẹli 20

Isikiẹli 20:15-23